Lo que a continuación aparece es una muestra abreviada de uno de los caminos que contiene el pack de caminos africanos de un Odu determinado, puede comprarlo desde aquí (El pack, incluye: 16 caminos inéditos, 3 medicinas, tabúes, Orisas asociados, profesiones y nombres).
Camino de la felicidad y la riqueza de Eiogbe
Otoo-too-too
Otoo-too-too
Otooto laa ko’le
Ogbon ta aa fii ko’le
Ko to eyi taaa fii gbe’nu u re
Dia fun Orunmila
Nijo ti Ajogun merin ka won mo’le l’Otu Ife
Ti Baba le won, le won
Ti won o lo
Para obtener el Ire en Oyekun Meji
Opele lo yo tan
Lo da’kun de’le
Dia fun Prenguede
Tii se yeye Ojumo mo
Ebo ni wo ni ko waa se
Subir
Para mejorar la suerte con Ifá en Iwori Meji
Eni a ba wa’de laa baa re’le
Eni aja ba wa l’aja nbaa lo
Dia fun Eleji-Iwori
Ti yoo te’ju ire omo Akapo o re girigiri
Ebo ni won ni ko se
Para el Iré de la vida en Odi Meji
Otootootoo
Oroorooroo
Ogiri totoo hunhun
Dia fun Orunmila
Baba yoo nire gbogbo
Nigba to gberin gberin
Ebo ni won ni won ni ko se
Ese Ifa para adquirir todas las cosas buenas en Iroso Meji
Akerese Owinni
Owinni naa Akerese
Dia fun Oniweere
Omo ojo owuro ti nb’olowo n’inu
Igbati o nsunkun oun o r’ire gbogbo
Ebo ni won ni ko se
Ese Ifa para el éxito y los logros de Ojuani Meji
Eku sanyin
Eja sanyin
Dia fun Ope Eluju
Ti yoo maa rin t’aje t’aje
Ebo ni won ni ko se
Camino de la Prosperidad de Obara Meji
A o m’ori afoju l’egbe
A o m’ese osika l’ona
A o m’ori oloye l’awujo
Dia fun Eji-Erindinlogun Orodu
Won nlo ree se’boru nile Olofin
Ebo ni won ni ki won se
Camino del Éxito de Okana Meji
Okan balabala
Awo Omu lo dia f’Omu
Omu n’torun bo wale Aye
O nraye agbejo
Ebo ni won ni ko waa se
O gb’ebo, o ru’bo
Ko pe, ko jinna
E wa ba’ni b’ewa
E wa wo’re o
Ese Ifa para la suerte en el amor y en la pareja de Ogunda Meji.
E maa see nso
A o maa wo bi e o ti see si
Dia fun Elerere Ogogo
Omo abapo ire gbogbo wonti-wonti lowo Olodunmare
Igbati o nt’orun bo wa’le aye
Ebo ni won ni ko waa se
Camino para obtener buena salud en Osa Meji.
On’ile eti oja nii wo irawo saasaa l’oke
Dia fun kutu
Ti nt’orun bo wa’ye
Ti yoo si fi gbogbo ara K’aje wa’le
Ebo ni won ni ko waa se
Ese Ifa para obtener pareja estable en Ika Meji.
Aagba ohun won ni njo o se’gbo
Ijokun ohun won ni njo o se odan
Keekee nii ba won-on s’Oyo Ajaka
Dia fun Oluweri
Eyi ti won o fi Oko fun ni lenje-lenje
Ebo ni won ni ko waa se
Ese Ifá para tener siempre el favor de Olodumare.
Ologbon o ta koko omi s’eti aso
Moranmoran o mo’ye iyepe ile
Arinnaka o de’bi ile gbe pekun
Gun’gi-gun’gi ko gun’gi re koja ewe
Dai fun Orunmila
Baba nsawo lo Ilu Aanu
Ebo ni won ni ko waa se
Para obtener el Ire por Otura Meji.
Akala Ipapo nii f’ese mejeeji gbe-kolo-mi gbe-kolo-mi
Dia fun awon ara Ode Ihehuje
Ebo Ire gbogbo ni won ni ko waa se
Camino de Ifa de la rentabilidad de Irete Meji.
Iyan Bemubemu lo kun inu igba
Oro Bemubemu ko kun ikun agbalagba
Dia fun Ilemajeyi
Ti yoo k’ere aye je
Ebo ni won ni ko waa se
Camino de Oshe Meji para convertirse en el cabeza de familia.
Idanndan ni atupa ile
Dia fun won l’ode Ilu-Nla
Ibi won gbe nbi Olu l’omo
Ebo ni won ni ko waa se
Camino del liderazgo de Ofun Meji
A su’re a ka’san
A rin’rin gbere a ka’san
A kii l’eni ni Mosan
Ka mu aipon
Dia fun Oju
Ti nlo ree je Oloja l’awujo ara
Ebo ni won ni ko waa se